Traducción generada automáticamente

Èmi Ló Kàn
Qdot
Soy Yo
Èmi Ló Kàn
Hijo, hijo de MoriahỌmọ ọmọ Mọriamọ
(2T en el ritmo)(2T up on the beat)
Qdot es mi nombreQdot lórúkọ mi
(Esa parte también se va)(Kúró ńbẹ̀ yẹn náà)
Se hizo primero en la tierraÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
Se hizo segundo en la tierraÓ ṣe kejì lulẹ̀
Se hizo tercero en la tierraÓ ṣe kẹta lulẹ̀
Por favor, no dejen que sea el cuartoẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(Soy yo)(Èmi ló kàn)
Traigan esto aquí (Soy yo)Ẹ gbé kiní yìí wá (Èmi ló kàn)
¿Qué es esto, qué soy yo? (Soy yo)Kiní yìí, kiní mi (Èmi ló kàn)
Un ángel que reparte bendiciones (Soy yo)Áńgẹ́lì tó ń pín ire (Èmi ló kàn)
Reparte una bendición a mí (Soy yo)Pín ire kàn mí (Èmi ló kàn)
Debo tener dinero (Soy yo)Mo gbọ́dọ̀ lówó (Èmi ló kàn)
El hijo de Dios no debe fracasar (Soy yo)Ọmọ Ọlọ́run ò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ṣó (Èmi ló kàn)
Bendiciones de dinero (Soy yo)Ire owó (Èmi ló kàn)
Bendiciones de hijos (Soy yo)Ire ọmọ (Èmi ló kàn)
Bendiciones (Soy yo)Àlùbáríkà (Èmi ló kàn)
Londres en América (Soy yo)London wọnú Amẹ́ríkà (Èmi ló kàn)
Dubái en Canadá (Soy yo)Dubai wọ Kánádà (Èmi ló kàn)
Así es como se habla de mí (Soy yo)Báyìí kọ́ là ń ṣe kọ́ ọ̀rọ̀ mi (Èmi ló kàn)
Tres visiones, no debo ser un ladrón (Soy yo)Ìran mẹ́ta, ò gbọ́dọ̀ di òṣì (Èmi ló kàn)
Mi cabeza, llena de dinero (Soy yo)Kórí mi, dorí owó (Èmi ló kàn)
Mi cabeza, llena de bendiciones (Soy yo)Kórí mi, dorí àpèsìn (Èmi ló kàn)
Todo lo que necesito es bendición (Soy yo)All I need is blessing (Èmi ló kàn)
Se hizo primero en la tierraÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
Se hizo segundo en la tierraÓ ṣe kejì lulẹ̀
Se hizo tercero en la tierraÓ ṣe kẹta lulẹ̀
Por favor, no dejen que sea el cuartoẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(Soy yo)(Èmi ló kàn)
Este año es mi año (Soy yo)Ọdún yìí, ọdún mi ni (Èmi ló kàn)
Mi cabeza no debe inclinarse (Soy yo)Orí mi má já mi kúnlẹ̀ (Èmi ló kàn)
Dios, el camino de la pureza (Soy yo)Ọlọ́run ọ̀nà ìwà mímọ́ (Èmi ló kàn)
Dios, el que responde (Soy yo)Ọlọ́run Asakiatu (Èmi ló kàn)
¿Acaso nuestro ángel no está bien? (Soy yo)Màlékà wa ló dà? (Èmi ló kàn)
¿El mundo no me dice: mi Dios está bien? (Soy yo)Káyé má bí mi pé: ọlọ́run mi dà? (Èmi ló kàn)
Los que tienen boca, hablan (Soy yo)Àwọn ẹlẹ́nu ṣọ-ṣọ-ṣọ (Èmi ló kàn)
Los que tienen boca, murmuran (Soy yo)Àwọn ẹlẹ́nu ṣo-ṣo-ṣo (Èmi ló kàn)
Ellos deben hablar de lo que no saben (Soy yo)Wọ́n dẹ̀ máa sọ ìsọkúsọ (Èmi ló kàn)
Mira la gloria de tu Biblia (Soy yo)Wo ọlá Bíbélì rẹ (Èmi ló kàn)
Mira la gloria de tu Corán (Soy yo)Wo ọlá Kùránì rẹ (Èmi ló kàn)
Mira la gloria de lo que mis padres tienen (Soy yo)Wo ọlá kiní àwọn baba mi kàn (Èmi ló kàn)
Que suene fuerte (Soy yo)Tó dún woroworo (Èmi ló kàn)
Padre, no me dejes caer (Soy yo)Baba má jẹ́ n pòfo (Èmi ló kàn)
Padre, haz milagros en mi vida (Soy yo)Baba ṣe ìyanu láyé mi (Èmi ló kàn)
Que yo sea el que tiene la cabeza en alto (Soy yo)Kí n yẹ fi orí olórí tọ́ọ́rọ́ (Èmi ló kàn)
Se hizo primero en la tierraÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
Se hizo segundo en la tierraÓ ṣe kejì lulẹ̀
Se hizo tercero en la tierraÓ ṣe kẹta lulẹ̀
Por favor, no dejen que sea el cuartoẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(Soy yo)(Èmi ló kàn)
Mi tiempo ha llegado (Soy yo)Ìgbà mi ló dé (Èmi ló kàn)
El hijo de Moriah quiere la corona (Soy yo)Ọmọ Mọriamọ fẹ́ gba adé (Èmi ló kàn)
Díganle a Sunny al rey (Soy yo)Ẹ sọ fún Sunny al'Ádé (Èmi ló kàn)
Lo que se dice se lo diré a Shango (Soy yo)Ọ̀rọ̀ tẹ́ bá sọ fún Ṣàngó (Èmi ló kàn)
Shango se lo dirá a Oya (Soy yo)Ṣàngó máa sọ fún Ọya (Èmi ló kàn)
Díganle a Dangote que le diga a Okoya (Soy yo)Ẹ sọ fún Dangote pé kó sọ fún Ọkọ́ya (Èmi ló kàn)
Yo también quiero tener compasión por la gente (Soy yo)Èmi náà fẹ́ ṣàánú ènìyàn (Èmi ló kàn)
Como Dende en Ílaró (Soy yo)Bí ti Dende n'Ílaró (Èmi ló kàn)
MC está gastando en Yémisi (Soy yo)MC ń fówó Yẹ́misí (Èmi ló kàn)
Conozco a Riliwan Cooler (Soy yo)Mo mọ Riliwan Cooler (Èmi ló kàn)
Soy Paso (Soy yo)Èèyàn Paso (Èmi ló kàn)
El que tiene más que el rico (Soy yo)Alágbé tó bá lá ju olówó (Èmi ló kàn)
El que vende coches (Soy yo)Arówólò lòun ta mọ́tò (Èmi ló kàn)
Doctor Brown (Soy yo)Doctor Brown (Èmi ló kàn)
Lánre Typical (Soy yo)Lánre Typical (Èmi ló kàn)
Si digo: Un-un un-un (Soy yo)Tí n bá ní: Un-un un-un (Èmi ló kàn)
Si digo: en-en en-en (Soy yo)Tí n bá ní: ẹn-ẹn ẹn-ẹn (Èmi ló kàn)
Mira, yo entiendo (Soy yo)Wò, èmi lòye (Èmi ló kàn)
No hablo por hablar (Soy yo)Mi ò fi gbogbo ẹnu sọ̀rọ̀ (Èmi ló kàn)
No me dejen fuera de la conversación (Soy yo)Kàn má tì mí mọ́ kọ̀rọ̀ (Èmi ló kàn)
Conocemos a la gente en Abúja (Soy yo)A mọ èèyàn l'Ábùújá (Èmi ló kàn)
2T va a sonar y va a gustar (Soy yo)2T máa lùlù ó máa dùn (Èmi ló kàn)
Cuando suene, va a gustar (Soy yo)Tó bá ti dún, ó dẹ̀ máa dùn (Èmi ló kàn)
Se hizo primero en la tierraÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
Se hizo segundo en la tierraÓ ṣe kejì lulẹ̀
Se hizo tercero en la tierraÓ ṣe kẹta lulẹ̀
Por favor, no dejen que sea el cuartoẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(Soy yo)(Èmi ló kàn)
2T en la mezcla2T on the mix



Comentarios
Envía preguntas, explicaciones y curiosidades sobre la letra
Forma parte de esta comunidad
Haz preguntas sobre idiomas, interactúa con más fans de Qdot y explora más allá de las letras.
Conoce a Letras AcademyRevisa nuestra guía de uso para hacer comentarios.
¿Enviar a la central de preguntas?
Tus preguntas podrán ser contestadas por profesores y alumnos de la plataforma.
Comprende mejor con esta clase: