visualizaciones de letras 11

Military

Asake

Letra

    Uh
    Àwọn ló ń l'ẹ́nu
    Wọ́n kò ń máa sọ lò
    Ti ò bá ti affẹ́ct bank mi, kó máa sọ̀rọ̀
    Making money, mo wà focused
    Military régime, show love
    La mèdàl ló ń ọmọ tó ń sọ
    Ó kan máa sáré, sáré, sáré, o ò le bá a bó ti lọ
    Èmi kò ní Ọlọ́run ni, Ọlọ́run ló dá a mi
    Òyìnbó kòrò l'ẹ́nu mi

    For my set, who get money pass me?
    Kò má sì
    Èmi kàn like low-key
    Achievement all over the world, wọ́n mọ̀
    Stubborn, you fit do am? Ó yá, go front
    Make I stop, make I chill
    I fit dey go from now till early mó̩-mó̩
    Ọmọ Ọlọ́run
    Mi ò gbọ́dọ̀ máa sọ̀rọ̀ too much
    Pause if you must, but don't stop

    Shout out Olamide Badoo
    Ìdàn

    Mo lè drop album l'ọ̀lá ti inú bá bì mi
    Zero tracklist, mo lè gbé wọn sáré ni
    Mo lè ní kí wọ́n lọ gba wọ́n lẹ́ti ni, but máa stop it torí pé mo ṣiṣẹ́ dé bí ni
    Talk your shit, mo mọ̀ pé o máa ń kó bà mi
    Ọmọ, fuck that shit, kúrò níbí ni
    Ṣé àgídí ni?
    Bọ̀bọ̀, bọ̀bọ̀, má gb'ọ̀wọ́ mi
    Alákọ̀bá jìná s'ọ̀dọ̀ mi

    For my set, who get money pass me?
    Kò má sì
    Èmi kàn like low-key
    Achievement all over the world, wọ́n mọ̀
    Stubborn, you fit do am? Ó yá, go front
    Make I stop, make I chill
    I fit dey go from now till early mó̩-mó̩
    Ọmọ Ọlọ́run
    Mi ò gbọ́dọ̀ máa sọ̀rọ̀ too much
    Pause if you must, but don't stop


    Comentarios

    Envía preguntas, explicaciones y curiosidades sobre la letra

    0 / 500

    Forma parte  de esta comunidad 

    Haz preguntas sobre idiomas, interactúa con más fans de Asake y explora más allá de las letras.

    Conoce a Letras Academy

    ¿Enviar a la central de preguntas?

    Tus preguntas podrán ser contestadas por profesores y alumnos de la plataforma.

    Comprende mejor con esta clase:

    0 / 500

    Opciones de selección