visualizaciones de letras 6
Letra

    Oun gbogbo to fo s'oke, o ṣí n bọ wa'lẹ
    Ìyẹn l'ọrọ ile aye
    Oun ire ta m'ọwọ wa ṣe, ni yi o sun wa s'ayọ o
    Ire awa ko ni kọjá

    Oṣíṣẹ ki ṣ'ofo, ireti le pe l'oju ẹda o
    Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa
    Lo n pe o, lo n pe mi o
    O n pe o, o n pe mi o
    O n ba wa wi

    Wi f'ẹni to n bẹru, ko ma ṣe ṣ'iyemeji
    Igboya ni t'olubori
    Sọ f'àwọn to n ṣe'paya o, duro ko ma-ma mi'kan o
    Aforiti l'ọpá ogo

    Ọmọ ọgbọn kii foya, ileri ko ni ṣá ii ṣẹ o
    Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa
    Lo n pe o, lo n pe mi o
    O n pe o, o n pe mi o
    O n ba wa wi
    Irinajo ọmọ ẹda o n la ti loke-nilẹ
    Ìyẹn l'ọrọ ile aye
    Oun ire ta fẹ gbeṣe, ni yi o sun wa si'dunnu
    Ayọ abakalẹ

    Oṣíṣẹ kii ṣ'ofo, ireti le pe l'oju ẹda o
    Òtítọ ẹri-ọkàn, ṣé b'oun lo n pe wa
    Lo n pe o, lo n pe mi o
    O n pe o, o n pe mi o
    O n ba wa wi

    O n pe o, o n pe mi o
    O n ba wa wi o
    O n pe o, o n pe mi o
    O n ba wa wi
    Ṣé b'on, o n pe o, o n pe mi o
    O n ba wa wi o
    O n pe o, o n pe mi o
    Ṣé bo n ba wa wi
    O n pe o


    Comentarios

    Envía preguntas, explicaciones y curiosidades sobre la letra

    0 / 500

    Forma parte  de esta comunidad 

    Haz preguntas sobre idiomas, interactúa con más fans de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band y explora más allá de las letras.

    Conoce a Letras Academy

    ¿Enviar a la central de preguntas?

    Tus preguntas podrán ser contestadas por profesores y alumnos de la plataforma.

    Comprende mejor con esta clase:

    0 / 500

    Opciones de selección