Suscríbete

Traducción automática

Visualizaciones de la letra 67

Èmi Ló Kàn

Qdot

Letra

C'est Moi

Èmi Ló Kàn

Gamin, gamin MọriamọỌmọ ọmọ Mọriamọ
(2T sur le beat)(2T up on the beat)
Qdot c'est mon nomQdot lórúkọ mi
(Sors de là aussi)(Kúró ńbẹ̀ yẹn náà)

C'est la première fois iciÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
C'est la deuxième fois iciÓ ṣe kejì lulẹ̀
C'est la troisième fois iciÓ ṣe kẹta lulẹ̀
S'il vous plaît, ne laissez pas ça être la quatrièmeẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(C'est moi)(Èmi ló kàn)

Apportez-moi ça (C'est moi)Ẹ gbé kiní yìí wá (Èmi ló kàn)
Qu'est-ce que c'est, qu'est-ce que je suis (C'est moi)Kiní yìí, kiní mi (Èmi ló kàn)
Un ange qui partage le bien (C'est moi)Áńgẹ́lì tó ń pín ire (Èmi ló kàn)
Partage juste un peu avec moi (C'est moi)Pín ire kàn mí (Èmi ló kàn)
Je dois avoir de l'argent (C'est moi)Mo gbọ́dọ̀ lówó (Èmi ló kàn)
L'enfant de Dieu ne doit pas être en détresse (C'est moi)Ọmọ Ọlọ́run ò gbọ́dọ̀ ṣẹ́ṣó (Èmi ló kàn)
Le bien de l'argent (C'est moi)Ire owó (Èmi ló kàn)
Le bien de l'enfant (C'est moi)Ire ọmọ (Èmi ló kàn)
La bénédiction (C'est moi)Àlùbáríkà (Èmi ló kàn)
Londres dans l'Amérique (C'est moi)London wọnú Amẹ́ríkà (Èmi ló kàn)
Dubaï vers le Canada (C'est moi)Dubai wọ Kánádà (Èmi ló kàn)
C'est comme ça qu'on fait, pas de blabla (C'est moi)Báyìí kọ́ là ń ṣe kọ́ ọ̀rọ̀ mi (Èmi ló kàn)
Trois visions, ne doivent pas devenir des mensonges (C'est moi)Ìran mẹ́ta, ò gbọ́dọ̀ di òṣì (Èmi ló kàn)
Ma tête, vers l'argent (C'est moi)Kórí mi, dorí owó (Èmi ló kàn)
Ma tête, vers la bénédiction (C'est moi)Kórí mi, dorí àpèsìn (Èmi ló kàn)
Tout ce dont j'ai besoin, c'est d'une bénédiction (C'est moi)All I need is blessing (Èmi ló kàn)

C'est la première fois iciÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
C'est la deuxième fois iciÓ ṣe kejì lulẹ̀
C'est la troisième fois iciÓ ṣe kẹta lulẹ̀
S'il vous plaît, ne laissez pas ça être la quatrièmeẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(C'est moi)(Èmi ló kàn)

Cette année, c'est mon année (C'est moi)Ọdún yìí, ọdún mi ni (Èmi ló kàn)
Ma tête ne doit pas me faire tomber (C'est moi)Orí mi má já mi kúnlẹ̀ (Èmi ló kàn)
Dieu, le chemin de la pureté (C'est moi)Ọlọ́run ọ̀nà ìwà mímọ́ (Èmi ló kàn)
Dieu Asakiatu (C'est moi)Ọlọ́run Asakiatu (Èmi ló kàn)
Notre Malek est-il bon ? (C'est moi)Màlékà wa ló dà? (Èmi ló kàn)
Que le monde ne me demande pas : est-ce que mon Dieu est bon ? (C'est moi)Káyé má bí mi pé: ọlọ́run mi dà? (Èmi ló kàn)
Les bavards (C'est moi)Àwọn ẹlẹ́nu ṣọ-ṣọ-ṣọ (Èmi ló kàn)
Les bavards (C'est moi)Àwọn ẹlẹ́nu ṣo-ṣo-ṣo (Èmi ló kàn)
Ils vont dire des mensonges (C'est moi)Wọ́n dẹ̀ máa sọ ìsọkúsọ (Èmi ló kàn)
Regarde la gloire de ta Bible (C'est moi)Wo ọlá Bíbélì rẹ (Èmi ló kàn)
Regarde la gloire de ton Coran (C'est moi)Wo ọlá Kùránì rẹ (Èmi ló kàn)
Regarde la gloire de mes ancêtres (C'est moi)Wo ọlá kiní àwọn baba mi kàn (Èmi ló kàn)
Qui est doux comme du miel (C'est moi)Tó dún woroworo (Èmi ló kàn)
Papa, ne sois pas avare (C'est moi)Baba má jẹ́ n pòfo (Èmi ló kàn)
Papa, fais des miracles dans ma vie (C'est moi)Baba ṣe ìyanu láyé mi (Èmi ló kàn)
Que je puisse être couronné (C'est moi)Kí n yẹ fi orí olórí tọ́ọ́rọ́ (Èmi ló kàn)

C'est la première fois iciÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
C'est la deuxième fois iciÓ ṣe kejì lulẹ̀
C'est la troisième fois iciÓ ṣe kẹta lulẹ̀
S'il vous plaît, ne laissez pas ça être la quatrièmeẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(C'est moi)(Èmi ló kàn)

Mon heure est arrivée (C'est moi)Ìgbà mi ló dé (Èmi ló kàn)
L'enfant Mọriamọ veut la couronne (C'est moi)Ọmọ Mọriamọ fẹ́ gba adé (Èmi ló kàn)
Dites à Sunny al'Ádé (C'est moi)Ẹ sọ fún Sunny al'Ádé (Èmi ló kàn)
Ce que je dis à Ṣàngó (C'est moi)Ọ̀rọ̀ tẹ́ bá sọ fún Ṣàngó (Èmi ló kàn)
Ṣàngó va le dire à Ọya (C'est moi)Ṣàngó máa sọ fún Ọya (Èmi ló kàn)
Dites à Dangote de le dire à Ọkọ́ya (C'est moi)Ẹ sọ fún Dangote pé kó sọ fún Ọkọ́ya (Èmi ló kàn)
Je veux aussi avoir pitié des gens (C'est moi)Èmi náà fẹ́ ṣàánú ènìyàn (Èmi ló kàn)
Comme Dende à Ílaró (C'est moi)Bí ti Dende n'Ílaró (Èmi ló kàn)
MC dépense pour Yẹ́misí (C'est moi)MC ń fówó Yẹ́misí (Èmi ló kàn)
Je connais Riliwan Cooler (C'est moi)Mo mọ Riliwan Cooler (Èmi ló kàn)
C'est un Paso (C'est moi)Èèyàn Paso (Èmi ló kàn)
Un riche qui a plus que les riches (C'est moi)Alágbé tó bá lá ju olówó (Èmi ló kàn)
Un entrepreneur qui vend des voitures (C'est moi)Arówólò lòun ta mọ́tò (Èmi ló kàn)
Docteur Brown (C'est moi)Doctor Brown (Èmi ló kàn)
Lánre Typical (C'est moi)Lánre Typical (Èmi ló kàn)
Quand je dis : Un-un un-un (C'est moi)Tí n bá ní: Un-un un-un (Èmi ló kàn)
Quand je dis : en-ẹn en-ẹn (C'est moi)Tí n bá ní: ẹn-ẹn ẹn-ẹn (Èmi ló kàn)
Regarde, c'est moi qui comprends (C'est moi)Wò, èmi lòye (Èmi ló kàn)
Je ne dis pas tout (C'est moi)Mi ò fi gbogbo ẹnu sọ̀rọ̀ (Èmi ló kàn)
Ne me mets pas dans des histoires (C'est moi)Kàn má tì mí mọ́ kọ̀rọ̀ (Èmi ló kàn)
On connaît les gens à Abouja (C'est moi)A mọ èèyàn l'Ábùújá (Èmi ló kàn)
2T va faire du bon son (C'est moi)2T máa lùlù ó máa dùn (Èmi ló kàn)
Quand ça sonne bien, ça sonne encore mieux (C'est moi)Tó bá ti dún, ó dẹ̀ máa dùn (Èmi ló kàn)

C'est la première fois iciÓ ṣe kìn-ín-ní lulẹ̀
C'est la deuxième fois iciÓ ṣe kejì lulẹ̀
C'est la troisième fois iciÓ ṣe kẹta lulẹ̀
S'il vous plaît, ne laissez pas ça être la quatrièmeẸ dákún, ẹ má jẹ́ kó ṣe kẹrin
(C'est moi)(Èmi ló kàn)

2T au mix2T on the mix


Comentarios

Envía preguntas, explicaciones y curiosidades sobre la letra

0 / 500

Forma parte  de esta comunidad 

Haz preguntas sobre idiomas, interactúa con más fans de Qdot y explora más allá de las letras.

Conoce a Letras Academy

¿Enviar a la central de preguntas?

Tus preguntas podrán ser contestadas por profesores y alumnos de la plataforma.

Comprende mejor con esta clase:

0 / 500

Opciones de selección