Suscríbete
visualizaciones de letras 4

OBT (One Big Transaction) (feat. Bhadboi OML)

Shoday

Oh, baba yẹ, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi
One big transaction, tó ma change story mi
Malaika tó n gbé're, jọ wá gbé'rẹ s'odo mi
Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (ob—, Obah)
Oh my maye, ma ma k'ohùn mi (wah dem a say?)
One big transaction, to ma change story mi
Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pín'rẹ d'odọ̀ mi

Wọn ni Naija ṣI ma dùn, but you dey America
E go better la ti n gbó la t'aye Abacha
Owo t'ọmọde bá kọ́ rí, á fi jẹ akara
If I see first money, mo ma sá lọ Canada

Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (shoday, kí lo dé?)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (hum)
One big transaction, to ma change story mi
Malaika tó n pín'rẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (oh, babá yè)
Oh, babá ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, tó ma change story mi (ehn)
Malaika tó n pínrẹ́, jọ̀wọ́ pin're d'odo mi (oh, babá yè)

Ibí e ní gbégbé kò ma gbé, ibè ló ma gbé (ibè ló má gbé)
Ọjà to ni gbégbé kò ma gbé, gbogbo ẹ ló ma gbé (gbogbo ẹ ló ma gbé)
Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister
Oh my maye ye-ye, wa gbé mi trabaye, ye-ye-ye
Ayy, it's going, it's going, olomi kò ní s'oṣI, kò ní s'ofo
They're trolling their father, I'm stoning pẹ̀lú kpoli, pẹ̀lú coco
Kò sí problem, kò sí yawa, kò sí story, kò sí glory, ọmọ ologo
Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ́ (dorime fún ọmọ ọpẹ́)
Ọmọ oro mi wá pẹ (ọmọ oro mi wá pẹ)

Oh, baba ye
Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, tó ma change story mi (ehn)
Malaika tó n pín're, jọ̀wọ́ pín're d'odo mi
Oh, baba ye
Oh, baba ye, dáhùn s'ọ̀rọ̀ mi (dáhùn, dáhùn, dáhùn, dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma k'ohùn mi (ma ma k'ohùn mi)
One big transaction, to ma change story mi (ehn)
Malaika tó n gbé'rẹ, jọ wá gbé'rẹ d'odo mi

Escrita por: Marcel Akunwata, Shodade Salomon Segun, Koham Oladimeji Akinyinka, Tonade Sodiq Olamide, Daniel Oluwagbemiro Owolabi. ¿Los datos están equivocados? Avísanos.

Comentarios

Envía preguntas, explicaciones y curiosidades sobre la letra

0 / 500

Forma parte  de esta comunidad 

Haz preguntas sobre idiomas, interactúa con más fans de Shoday y explora más allá de las letras.

Conoce a Letras Academy

¿Enviar a la central de preguntas?

Tus preguntas podrán ser contestadas por profesores y alumnos de la plataforma.

Comprende mejor con esta clase:

0 / 500

Opciones de selección